The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesTaha [Taha] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 37
Surah Taha [Taha] Ayah 135 Location Maccah Number 20
وَلَقَدۡ مَنَنَّا عَلَيۡكَ مَرَّةً أُخۡرَىٰٓ [٣٧]
Àti pé dájúdájú A ti ṣe oore fún ọ nígbà kan rí.