The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThose who set the ranks [As-Saaffat] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 103
Surah Those who set the ranks [As-Saaffat] Ayah 182 Location Maccah Number 37
فَلَمَّآ أَسۡلَمَا وَتَلَّهُۥ لِلۡجَبِينِ [١٠٣]
Nígbà tí àwọn méjèèjì juwọ́ jusẹ̀ sílẹ̀, tí (Ànábì ’Ibrọ̄hīm) sì dojú[1] (ọmọ) rẹ̀ bolẹ̀,