The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Beneficient [Al-Rahman] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 46
Surah The Beneficient [Al-Rahman] Ayah 78 Location Maccah Number 55
وَلِمَنۡ خَافَ مَقَامَ رَبِّهِۦ جَنَّتَانِ [٤٦]
Ọgbà Ìdẹ̀ra méjì ń bẹ fún ẹni tó bá páyà ìdúró rẹ̀ níwájú Olúwa rẹ̀.