The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Beneficient [Al-Rahman] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 53
Surah The Beneficient [Al-Rahman] Ayah 78 Location Maccah Number 55
فَبِأَيِّ ءَالَآءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ [٥٣]
Nítorí náà, èwo nínú àwọn ìdẹ̀ra Olúwa ẹ̀yin ènìyàn àti àlùjànnú ni ẹ máa pè ní irọ́?