The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Event, The Inevitable [Al-Waqia] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 3
Surah The Event, The Inevitable [Al-Waqia] Ayah 96 Location Maccah Number 56
خَافِضَةٞ رَّافِعَةٌ [٣]
ó máa mú (àwọn kan) wálẹ̀ (sínú Iná), ó sì máa gbé (àwọn kan) sókè (nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra).