The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesShe that disputes [Al-Mujadila] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 19
Surah She that disputes [Al-Mujadila] Ayah 22 Location Madanah Number 58
ٱسۡتَحۡوَذَ عَلَيۡهِمُ ٱلشَّيۡطَٰنُ فَأَنسَىٰهُمۡ ذِكۡرَ ٱللَّهِۚ أُوْلَٰٓئِكَ حِزۡبُ ٱلشَّيۡطَٰنِۚ أَلَآ إِنَّ حِزۡبَ ٱلشَّيۡطَٰنِ هُمُ ٱلۡخَٰسِرُونَ [١٩]
aṣ-Ṣaetọ̄n jẹgàba lé wọn lórí. Ó sì mú wọn gbàgbé ìrántí Allāhu. Àwọn wọ̀nyẹn ni ìjọ aṣ-Ṣaetọ̄n. Gbọ́! Dájúdájú ìjọ aṣ-Ṣaetọ̄n, àwọn ni ẹni òfò.