The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe heights [Al-Araf] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 111
Surah The heights [Al-Araf] Ayah 206 Location Maccah Number 7
قَالُوٓاْ أَرۡجِهۡ وَأَخَاهُ وَأَرۡسِلۡ فِي ٱلۡمَدَآئِنِ حَٰشِرِينَ [١١١]
Wọ́n sì wí pé: “Fún òun àti arákùnrin rẹ̀ lọ́jọ́,[1] kí o sì rán àwọn akónijọ² sí àwọn ìlú,