The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe heights [Al-Araf] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 15
Surah The heights [Al-Araf] Ayah 206 Location Maccah Number 7
قَالَ إِنَّكَ مِنَ ٱلۡمُنظَرِينَ [١٥]
(Allāhu) sọ pé: “Dájúdájú ìwọ ń bẹ nínú àwọn tí A óò lọ́ lára.”