The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThose who drag forth [An-Naziat] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 12
Surah Those who drag forth [An-Naziat] Ayah 46 Location Maccah Number 79
قَالُواْ تِلۡكَ إِذٗا كَرَّةٌ خَاسِرَةٞ [١٢]
Wọ́n wí pé: “Ìdápadà òfò nìyẹn nígbà náà (fún ẹni tó pè é ní irọ́.)”