The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThose who drag forth [An-Naziat] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 2
Surah Those who drag forth [An-Naziat] Ayah 46 Location Maccah Number 79
وَٱلنَّٰشِطَٰتِ نَشۡطٗا [٢]
Ó tún fi àwọn mọlāika tó ń fi ọ̀nà ẹ̀rọ̀ gba ẹ̀mí àwọn onígbàgbọ́ òdodo búra.