The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThose who drag forth [An-Naziat] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 26
Surah Those who drag forth [An-Naziat] Ayah 46 Location Maccah Number 79
إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَعِبۡرَةٗ لِّمَن يَخۡشَىٰٓ [٢٦]
Dájúdájú àríwòye wà nínú ìyẹn fún ẹni tó ń páyà (Allāhu).