The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThose who drag forth [An-Naziat] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 5
Surah Those who drag forth [An-Naziat] Ayah 46 Location Maccah Number 79
فَٱلۡمُدَبِّرَٰتِ أَمۡرٗا [٥]
Ó tún fi àwọn mọlāika tó ń ṣètò nínú sánmọ̀ àti ilé ayé pẹ̀lú àṣẹ Allāhu búra.