The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe Sun [Ash-Shams] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 12
Surah The Sun [Ash-Shams] Ayah 15 Location Maccah Number 91
إِذِ ٱنۢبَعَثَ أَشۡقَىٰهَا [١٢]
(Rántí) nígbà tí ẹni tí orí rẹ̀ burú jùlọ nínú wọn sáré dìde (láti gún ràkúnmí pa).