The Noble Qur'an Encyclopedia
Towards providing reliable exegeses and translations of the meanings of the Noble Qur'an in the world languagesThe morning hours [Ad-Dhuha] - Yoruba translation - Abu Rahima Mikael - Ayah 7
Surah The morning hours [Ad-Dhuha] Ayah 11 Location Maccah Number 93
وَوَجَدَكَ ضَآلّٗا فَهَدَىٰ [٧]
Ó sì rí ọ ní aláìmọ̀nà (ìyẹn ṣíwájú ìsọ̀kalẹ̀ ìmísí). Ó sì fi ọ̀nà mọ̀ ọ́.[1]